Report Abuse

Blog Archive

AD SPACE

Labels

Labels

About

Comments

recentcomments

Blogroll

Facebook

Skip to main content

OrikiIbeji Ejire ara Isokun Edun A gbori igi regrege Winino winini loju orogun Eji woro loju iya e O be kisi be kese O be sile elekisa O so o dalaso Okan mo ni n o bi Eji lo wole to mi Bu mi ki nba o rele Yin mi ki npada leyin re Nijo ejire ti daye ko jale ri Oju oloko ni se je tie Mo lepo nile Mo lewa loode Ejire eelaki maa bo lodo mi Ireke mi ree Aadun mi ree Mo fe bo ibeji oro Oniruuru omo lo nbe laye Ninu omo to je abami La gbe ri ibeji laarin won Eni ejiree nwuu bi Ki o yaa niwa tutu Tori pe osonu ile ko bi ejire Oninuure ni bedun Ejire okin maa so mi lokun lona ofun Iya onikaluku won o so kale Won abimo won okan soso pere Eni oninuure lOlorun oba nfun lore Eyin ko mo pe ore lejire ara isokun Iyawo mi lejo Emi naa le sodi wuke Ejire oriyaki maa bo lodo wa Atike atige laa fi sike ibeji Atowo atiyi lejire fii sike eni Oga lejire oriyaki laarin awon omo to nbe laye gbogbo

Hello, my name is Olaleye Emmanuel. A part time Blogger and a Financial analyst from Nigeria. I hold a Bachelor of science and Education Degree in Economics From Ekiti State University, Ado Ekiti, Nigeria.

Comments